Awon egbon mi lo ko egbe kan jo nigba naa, emi naa pelu won, mo n gberin leyin won, ohun to daa ti mo ni lo je ki n ta won yo.Odidi wakati meji ni Alaaja Odusote lo lodo e ko too di pe o pada sile.Okan ninu awon orin e to ko bayii pe, Lekeleke ki i doti, Oba Oluwa ma je ka doti o, lo fi sin ore e pada sile lojo naa.E fara bale ki e ka ohun ti won ba Lati Owo Johnson Akinpelu ati TAOFIK AFOLABI so.
ALAAJI ADEMOLA GANIYU, AKOBI ALAAJA BATILI ALAKE Emi ni akobi Alaaja Batili Alake, eni odun metadinlogota ni mi bayii. Ohun ti a gbo nipa won ni pe ojo mejo ni won fi n lulu ti won n sere to fi di ojo ti won so won loruko. Omo meta ni mama won bi, akoko ni Ganiyu Seidu, ekeji ni Rasak, nigba ti mama je obinrin to wa laarin won. Seli ni won maa n lu ni gbogbo asiko yii, gbogbo ile Ijebu ni won ti maa n korin nigba naa. Mama mi ko lo sileewe rara, bo tile je pe o wu won lati lo, sugbon baba won ko je ki won lo. Lara awon ti won jo n korin nigba naa ni Silifa, Aduke, Alake ati Amope, eni to n lulu fun won n je Aliu. Lara awon isoro to koju won lasiko ti won gbe rekoodu jade ni ki awon to ba won gbe awo jade ma sanwo fun won. Taibat Amope ati Sikiratu Ayan ni won jo wa nita lasiko tawon mama bere orin. ![]() ARABINRIN OGUNBONA, OMO ALAAJI BATILI ALAKE TO N BA A KORIN Titi aye ni ma a maa ranti mama mi. Emi naa ba mama mi sise orin, sugbon oko mi ko je ki n korin. Mama je eni to ko ebi mora, o feran adura; to ba wa sile mi bayii, o le fi ogbon iseju sadura. Sugbon ohun ti mo maa n so fun won ni pe ki won ma tori pe won fe oko nile wa, ki won maa kunle fun mi. Ohun to maa n so fun mi ni pe mi o gbodo fi oun sile, bee lemi naa ki i fi i sile. Nise lo ba mi ya foto, to sadura fun awon eeyan, to tun fun awon aafaa lowo. O loun dupe pe nnkan ayo omo naa soju oun, mo ni emi naa ba a dupe. ![]() Olorin ni Baba to bi mi, omo eyin onisakara kan ni nigba aye e. Emi ni akobi baba mi lobinrin, mo ranti daadaa pe mo maa n tele won lo sode-ere. Visual studio 2013 product keyIku baba mi ni ko je ki n kawe daadaa, mi o ka ju iwe kin-in-ni, Standard 1 lo. Odo egbon won kan ni mo gbe dagba, idale ni mama mi wa nigba naa.
0 Comments
Leave a Reply. |
AuthorSusan ArchivesCategories |